Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà púpọ̀ nínú wọn gbàgbọ́; àti nínú àwọn obìnrin Gíríkì ọlọ́lá, àti nínú àwọn ọkùnrin, kì í ṣe díẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:4-19