Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọn sì ti kọjá Áḿfípólì àti Apolóníà, wọ́n wá sí Tẹsalóníkà, níbi tí sínágọ́gù àwọn Júù wà:

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:1-4