Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n dé ọ̀kánkán Mísíà, wọ́n gbìyànjú láti lọ ṣí Bítíníà, ṣùgbọ́n Ẹ̀mí Jéṣù kò gbà fún wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:1-15