Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì wá, wọ́n sìpẹ̀ fún wọ́n, wọn sì mú wọn jáde, wọ́n sì bẹ̀ wọ́n pé, ki wọn jáde kúrò ni ìlú náà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:35-40