Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni Pọ́ọ̀lù fẹ́ kí ó bá òun lọ; ó sì mú un, ó sì kọ ọ́ ní ilà, nítorí àwọn Júù tí ó wà ní agbégbé wọ̀nyí: nítorí gbogbo wọn mọ̀ pé, Gíríkì ni baba rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:1-4