Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì lù wọ́n púpọ̀, wọ́n sọ wọ́n sínú túbú, wọ́n kìlọ̀ fún onítúbú kí ó pa wọ́n mọ́ dáradára:

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:21-32