Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sí n kọ́ni ní àṣà tí kò yẹ fún wa, àwa ẹni tí í ṣe ara Romu, láti gbà àti láti tẹ̀lé.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:14-28