Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti obìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ńjẹ́ Lìdíà, tí ó ń ta àwọn aró ẹlẹ́ṣè àlùkò, gbọ́ ọ̀rọ̀ wa, ọkàn ẹni tí Olúwa ṣí láti fetísì ohun tí a tí ẹnu Pọ́ọ̀lù sọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:9-22