Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ibẹ̀ àwa sì lọ si Fílípì, Ìlú kan tí (àwọn ara Róòmù) tẹ̀dó tí í ṣe olú ìlú yìí fún ọjọ́ mélòókán.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:4-17