Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run, tí ó jẹ́ olúmọ-ọkàn, sì jẹ́ wọn lẹ́rìí, ó fún wọn ni Ẹ̀mí Mímọ́, gẹ́gẹ́ bí àwa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:1-10