Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Pọ́ọ̀lù yan Sílà, ó sì lọ, bí a ti fi lé oore-ọ̀fẹ́ Olúwa lọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:34-41