Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bánábà sì pinnu rẹ̀ láti mú Jòhánù lọ pẹ̀lú wọn, ẹni tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Máàkù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:28-41