Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ nígbà tí wọ́n sì fi wọ́n sílẹ̀ láti lọ, wọ́n sọ̀kalẹ̀ wá si Áńtíókù: nígbà tí wọn sì pé àwọn ìjọ pọ̀, wọn fi ìwé náà fún wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:25-38