Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè nígbà àtijọ́, sá ní àwọn ti ń wàásù rẹ̀, ni ìlú gbogbo, a máa ń kà á nínú sínágọ́gù ni ọjọ́jọ́ ìsinmi.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:13-24