Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ǹjẹ́ ìmọ̀ràn tèmi ni pé, kí a máa ṣe yọ àwọn ti aláìkọlà ti ó yípadà sí Ọlọ́run lẹ́nu.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:11-24