Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí àwọn ènìyàn ìyókù lè máa wá Olúwa,àti gbogbo àwọn aláìkọlà tí a ń fi orúkọ mi pè.’ni Olúwa wí, ta ni ó ń ṣe nǹkan wọ̀nyí

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:13-27