Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Símóòní ti róyìn bí Ọlọ́run ti kọ́kọ́ bojúwo àwọn aláìkọlà, láti yàn ènìyàn nínú wọn fún orúkọ rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:4-18