Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin kan sí jókòó ni Lísírà, ẹni tí ẹsẹ̀ rẹ̀ kò mókun, arọ láti inú ìyá rẹ̀ wá, tí kò rìn rí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:1-15