Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì dé, tí wọ́n sì pé ìjọ jọ, wọ́n ròhìn gbogbo ohun tí Ọlọ́run fi wọ́n ṣe, àti bí ó ti ṣí ilẹ̀kùn ìgbàgbọ́ fún àwọn aláìkọlà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:23-28