Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì ti yan àwọn alàgbà fún olúkúlùkù ìjọ, tí wọn sì ti fi àwẹ̀ gbàdúrà, wọn fi à wọ́n lé ẹni gbàgbọ́ Olúwa lọ́wọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:14-28