Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn aláìgbàgbọ́ Júù rú ọkàn àwọn aláìkọlà sókè, wọ́n sì mú wọn ni ọkàn ìkorò sí àwọn arákùnrin náà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:1-9