Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìran tí ó ti kọjá, ó faradà á fún gbogbo orílẹ̀-èdè, láti máa rìn ni ọ̀nà ti wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:11-21