Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí fún un ní ohùn rara pé, “Dìde dúró ṣánsán lórí ẹsẹ̀ rẹ!” Ó sì ń fò sókè, ó sì ń rìn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:6-18