Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:51-52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

51. Ṣùgbọ́n wọ́n gbọn eruku ẹsẹ̀ wọn sí wọn, wọn sì wá sí Ikóníónì.

52. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn si kún fún ayọ̀ àti fún Ẹ̀mí Mímọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13