Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn aláìkọlà sì gbọ́ èyí, wọ́n sì yín ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lógo: gbogbo àwọn tí a yàn sí ìyè àìnípẹ̀kun sì gbàgbọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:42-49