Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Pọ́ọ̀lù àti Bánábà sì ti ń jáde láti inú sínàgọ́gù, wọ́n bẹ̀bẹ̀ pé kí a sọ̀rọ̀ wọ̀nyí sí i fún wọn lọ́jọ́ ìsinmi tí ń bọ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:37-47