Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa rẹ̀ ni a ń dá olúkúlùkù ẹni tí ó gbàgbọ́ láre kúrò nínú ohun gbogbo, tí a kò lè dá yín láre rẹ̀ nínú òfin Mósè.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:29-40