Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì farahàn lọ́jọ́ púpọ̀ fún àwọn tí ó bá a gòkè láti Gálílì wá sí Jerúsálémù, àwọn tí í ṣe ẹlẹ́rìí rẹ̀ nísinsìn yìí fún àwọn ènìyàn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:26-32