Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n ti mú nǹkan gbogbo ṣẹ ti a kọ̀we nítorí rẹ̀, wọn sì sọ̀ ọ́ kalẹ̀ kúrò lórí igi wọ́n sì tẹ́ ẹ sí ibojì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:26-35