Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ará, ẹ̀yin ọmọ ìran Ábúráhámù, àti ẹ̀yin ti ó bẹ̀rù Ọlọ́run, àwa ni a rán ọ̀rọ̀ ìgbàlà yìí sí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:24-29