Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣáájú wíwa Jésù ni Jòhánù ti wàásù bamítísímù ìrónúpìwàdà fún gbogbo ènìyàn Isírẹ́lì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:19-29