Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni wọ́n sì bèèrè ọba; Ọlọ́run sì fún wọn ní Ṣọ́ọ̀lù ọmọ Kíṣì, ọkùnrin kan nínú ẹ̀ya Bẹ́ńjámínì, fún ogójì ọdún.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:20-29