Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pọ́ọ̀lù sì dìde dúró, ó sì juwọ́ sí wọn, ó ní, “Ẹ̀yin Ísírẹ́lì, àti ẹ̀yin ti ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ẹ fi etí sílẹ̀ sí mi!

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:13-22