Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà ti wọ́n sì là Págà kọjá, wọ́n wá sí Pìsìdíà ní Áńtíókù. Wọ́n sì wọ inú sínágọ́gù ní ọjọ́ ìsinmi, wọ́n sì jókòó.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:4-19