Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí baálẹ̀ rí ohun tí ó ṣe, ó gbàgbọ́, ẹnu sì yà á sì ẹ̀kọ́ Olúwa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:6-20