Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ ti ó kún fún àrékérekè gbogbo, àti fún ìwà-ìkà gbogbo, ìwọ ọmọ Èṣù, ìwọ kì yóò ha dẹ́kun láti máa yí ọ̀nà òtítọ́ Olúwa po?

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:1-15