Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà wọn fi Pétérù pamọ́ sínú túbú; ṣùgbọ́n ìjọ ń fi ìtara gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run fún un.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:1-7