Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì rí pé èyí ó dùn mọ́ àwọn Júù nińu, ó sì nawọ́ mú Pétérù pẹ̀lú. Ó sì jẹ́ ìgbà ọjọ́ àkàrà àìwú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:1-7