Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ilẹ̀ sì mọ́, ìrúkèrúdò díẹ̀ kọ́ ni ó wà láàrin àwọn ọmọ-ogun nípa ohun tí ó débá Pétérù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:17-25