Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó sì ti kan ìlẹ̀kùn ẹnu-ọ̀nà, ọmọbìnrin kan tí a n pè ní Ródà wá láti dáhùn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:11-19