Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí òun jẹ́ ènìyàn rere, ó sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́ àti fún ìgbàgbọ́; ènìyàn púpọ̀ ni a sì kà kún Olúwa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:20-26