Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni mo rántí ọ̀rọ̀ Olúwa, bí ó ti wí pé, ‘Jòhánù fi omi bamitíìsì nítóòtọ́; ṣùgbọ́n a ó fi Ẹ̀mí Mímọ́ bamitíìsì yín.’

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:15-23