Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀mí sì wí fún mi pé, kí èmi bá wọn lọ, ki èmi má ṣe kọminú ohunkóhun. Àwọn arákùnrin mẹ́fà wọ̀nyí sì bá mi lọ, a sì wọ ilé ọkùnrin náà:

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:2-14