Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn àpósítélì àti àwọn arákùnrin ti ó wà ni Jùdíà sì gbọ́ pé àwọn aláìkọlà pẹ̀lú ti gba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:1-4