Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì tí ṣàlàyé ohun gbogbo fún wọn, ó rán wọn lọ sí Jópà. A fi ran hàn Pétérù pẹ̀lú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:3-16