Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wọ̀ sí ilé Símónì aláwọ, tí ilé rẹ̀ wà létí òkun; òun ni yóò sọ fún ọ bí ìwọ ó ti ṣe.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:1-9