Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwa sì ni ẹlẹ́rì gbogbo ohun tí ó ṣe, ní ilẹ̀ àwọn Júù, àti ni Jerúsálémù. Ẹni tí wọ́n pa nípa gbígbékọ́ sí orí igi.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:29-48