Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwọ̀n wákàtí kẹ́sàn-án ọjọ́, ó rí nínú ìran kedere ańgẹ́lì Ọlọ́run kan wọlé tọ̀ ọ́ wá, ó sì wí fún un pé, “Kọ̀nélíù!”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:2-12