Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú rẹ̀ ni onírúurú ẹrankọ ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin wà, ati ohun tí ń rákò ni ayé àti ẹyẹ ojú ọ̀run.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:7-14