Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ó di dandan láti yan ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin wọn tí wọn ti ń bá wa rìn ni gbogbo àkókò tí Jésù Olúwa ń wọlé, tí ó sì jáde láàrin wa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:19-26